Mat 11:16
Mat 11:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Kí ni èmi ìbá fi ìran yìí wé? Ó dàbí àwọn ọmọ kékeré tí ń jókòó ní ọjà tí wọ́n sì ń ké pe àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn
Pín
Kà Mat 11Mat 11:16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn kili emi iba fi iran yi wé? O dabi awọn ọmọ kekeke ti njoko li ọjà ti nwọn si nkọ si awọn ẹgbẹ wọn
Pín
Kà Mat 11