Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 11:13YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori gbogbo awọn wolĩ ati ofin li o wi tẹlẹ ki Johanu ki o to de.
Pín
Mat 11YBCVMat 11:13BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà gbogbo òfin àti wòlíì ni ó sọtẹ́lẹ̀ kí Johanu kí ó tó dé.
Pín
Mat 11BMYOMat 11:13YCE(Yoruba Bible)
Nítorí títí di àkókò Johanu gbogbo àwọn wolii ati òfin sọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀.
Pín
Mat 11YCE