Mat 10:38
Mat 10:38 Yoruba Bible (YCE)
Bẹ́ẹ̀ ni, ẹnikẹ́ni tí kò bá gbé agbelebu rẹ̀, kí ó máa tẹ̀lé mi, kò yẹ ní tèmi.
Pín
Kà Mat 10Mat 10:38 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti kò ba si gbé agbelebu rẹ̀, ki o si mã tọ̀ mi lẹhin, kò yẹ ni temi.
Pín
Kà Mat 10