Mat 10:32
Mat 10:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́wọ́ mi níwájú ènìyàn, òun náà ni èmi yóò jẹ́wọ́ rẹ̀ níwájú Baba mi ní ọ̀run.
Pín
Kà Mat 10Mat 10:32 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitorina ẹnikẹni ti o ba jẹwọ mi niwaju enia, on li emi o jẹwọ pẹlu niwaju Baba mi ti mbẹ li ọrun.
Pín
Kà Mat 10