Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 10:17YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ẹ ṣọra lọdọ enia; nitori nwọn o fi nyin le ajọ igbimọ lọwọ, nwọn o si nà nyin ninu sinagogu wọn.
Pín
Mat 10YBCVMat 10:17BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ ṣọ́ra lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn nítorí wọn yóò fi yín le àwọn ìgbìmọ̀ ìgbèríko lọ́wọ́ wọn yóò sì nà yín nínú Sinagọgu.
Pín
Mat 10BMYOMat 10:17YCE(Yoruba Bible)
Ẹ kíyèsára lọ́dọ̀ àwọn eniyan, nítorí wọn yóo fà yín lọ siwaju ìgbìmọ̀ láti fẹ̀sùn kàn yín; wọn yóo nà yín ninu àwọn ilé ìpàdé wọn.
Pín
Mat 10YCE