Mat 1:7-11
Mat 1:7-11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Solomoni si bí Rehoboamu; Rehoboamu si bí Abia; Abia si bí Asa; Asa si bí Jehosafati; Jehosafati si bí Joramu; Joramu si bí Osia; Osia si bí Joatamu; Joatamu si bí Akasi; Akasi si bí Hesekiah; Hesekiah si bí Manasse; Manasse si bí Amoni; Amoni si bí Josiah; Josiah si bí Jekoniah ati awọn arakunrin rẹ̀, nigba ikolọ si Babiloni.
Mat 1:7-11 Yoruba Bible (YCE)
Solomoni bí Rehoboamu, Rehoboamu bí Abija, Abija bí Asa. Asa bí Jehoṣafati, Jehoṣafati bí Joramu, Joramu bí Usaya. Usaya bí Jotamu, Jotamu bí Ahasi, Ahasi bí Hesekaya. Hesekaya bí Manase, Manase bí Amosi, Amosi bí Josaya. Josaya bí Jekonaya ati àwọn arakunrin rẹ̀ ní àkókò tí wọn kó àwọn ọmọ Israẹli lẹ́rú lọ sí Babiloni.
Mat 1:7-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Solomoni ni baba Rehoboamu, Rehoboamu ni baba Abijah, Abijah ni baba Asa, Asa ni baba Jehoṣafati; Jehoṣafati ni baba Jehoramu; Jehoramu ni baba Ussiah; Ussiah ni baba Jotamu; Jotamu ni baba Ahaṣi; Ahaṣi ni baba Hesekiah; Hesekiah ni baba Manase; Manase ni baba Amoni; Amoni ni baba Josiah; Josiah sì ni baba Jekoniah àti àwọn arákùnrin rẹ̀ ní àkókò ìkólọ sí Babeli.