Mat 1:1-2
Mat 1:1-2 Yoruba Bible (YCE)
Èyí ni àkọsílẹ̀ ìran Jesu Kristi, ọmọ Dafidi, ọmọ Abrahamu. Abrahamu bí Isaaki, Isaaki bí Jakọbu, Jakọbu bí Juda ati àwọn arakunrin rẹ̀.
Pín
Kà Mat 1Mat 1:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ìwé ìran Jesu Kristi, ẹni tí í ṣe ọmọ Dafidi, ọmọ Abrahamu: Abrahamu ni baba Isaaki; Isaaki ni baba Jakọbu; Jakọbu ni baba Juda àti àwọn arákùnrin rẹ̀
Pín
Kà Mat 1Mat 1:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
IWE iran Jesu Kristi, ọmọ Dafidi ọmọ Abrahamu. Abrahamu bí Isaaki; Isaaki si bí Jakọbu; Jakọbu si bí Juda ati awọn arakunrin rẹ̀
Pín
Kà Mat 1