Mal 4:4 - Compare All Versions
Mal 4:4 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ ranti ofin Mose iranṣẹ mi, eyi ti mo pa li aṣẹ fun u ni Horebu fun gbogbo Israeli, pẹlu aṣẹ ati idajọ wọnni.
Pín
Mal 4 YBCVMal 4:4 YCE (Yoruba Bible)
“Ẹ ranti òfin ati ìlànà tí mo ti fún Mose, iranṣẹ mi, fún gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ní orí òkè Horebu.
Pín
Mal 4 YCEMal 4:4 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹ rántí òfin Mose ìránṣẹ́ mi, àwọn ìlànà àti òfin èyí tí mo fún un ní Horebu fún gbogbo Israẹli.”
Pín
Mal 4 BMYO