Mal 3:6
Mal 3:6 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA àwọn ọmọ ogun ní, “Nítorí pé èmi OLUWA kì í yipada, ni a kò fi tíì run ẹ̀yin ọmọ Jakọbu patapata.
Pín
Kà Mal 3Mal 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Èmi OLúWA kò yípadà. Nítorí náà ni a kò ṣe run ẹ̀yin ọmọ Jakọbu.
Pín
Kà Mal 3Mal 3:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori Emi li Oluwa, Emi kò yipada; nitorina li a kò ṣe run ẹnyin ọmọ Jakobu.
Pín
Kà Mal 3