Luk 3:19-20
Luk 3:19-20 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn Herodu tetrarki, ti o bawi nitori Herodia aya Filippi arakunrin rẹ̀, ati nitori ohun buburu gbogbo ti Herodu ti ṣe, O fi eyi pari gbogbo rẹ̀ niti o fi Johanu sinu tubu.
Pín
Kà Luk 3Ṣugbọn Herodu tetrarki, ti o bawi nitori Herodia aya Filippi arakunrin rẹ̀, ati nitori ohun buburu gbogbo ti Herodu ti ṣe, O fi eyi pari gbogbo rẹ̀ niti o fi Johanu sinu tubu.