Luk 24:2-3
Luk 24:2-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Òkúta ti yí kúrò ní ẹnu ibojì. Nígbà tí wọ́n sì wọ inú rẹ̀, wọn kò rí òkú Jesu Olúwa.
Pín
Kà Luk 24Luk 24:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nwọn si ba a, a ti yi okuta kuro li ẹnu ibojì. Nigbati nwọn wọ̀ inu rẹ̀, nwọn kò si ri okú Jesu Oluwa.
Pín
Kà Luk 24