Luk 1:45
Luk 1:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Alábùkún fún sì ni ẹni tí ó gbàgbọ́: nítorí nǹkan wọ̀nyí tí a ti sọ fún un láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá yóò ṣẹ.”
Pín
Kà Luk 1Luk 1:45 Bibeli Mimọ (YBCV)
Alabukun-fun si li ẹniti o gbagbọ́: nitori nkan wọnyi ti a ti sọ fun u lati ọdọ Oluwa wá yio ṣẹ.
Pín
Kà Luk 1