Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Lef 6:7YBCV(Bibeli Mimọ)

Alufa yio si ṣètutu fun u niwaju OLUWA, a o si dari rẹ̀ jì; nitori ohunkohun ninu gbogbo ohun eyiti o ti ṣe ti o si jẹbi ninu rẹ̀.

Lef 6:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Báyìí ní àlùfáà yóò ṣe ètùtù fún un ètùtù ìwẹ̀nùmọ́ níwájú OLúWA, a ó sì dáríjì í nítorí ohun tó ti ṣe tó sì mú un jẹ̀bi.”

Lef 6:7YCE(Yoruba Bible)

Alufaa yóo ṣe ètùtù fún ẹni náà níwájú OLUWA, OLUWA yóo sì dárí ohunkohun tí ó bá ṣe jì í.”