Lef 27:30
Lef 27:30 Yoruba Bible (YCE)
“Gbogbo ìdámẹ́wàá ilẹ̀ náà, kì báà jẹ́ ti èso ilẹ̀, tabi ti èso igi, ti OLUWA ni; mímọ́ ni fún OLUWA.
Pín
Kà Lef 27Lef 27:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“ ‘Gbogbo ìdámẹ́wàá ilẹ̀ náà yálà tí èso ilẹ̀ ni, tàbí tí èso igi, ti OLúWA ni. Mímọ́ ni fún OLúWA.
Pín
Kà Lef 27Lef 27:30 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ati gbogbo idamẹwa ilẹ na ibaṣe ti irugbìn ilẹ na, tabi ti eso igi, ti OLUWA ni: mimọ́ ni fun OLUWA.
Pín
Kà Lef 27Lef 27:30 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ati gbogbo idamẹwa ilẹ na ibaṣe ti irugbìn ilẹ na, tabi ti eso igi, ti OLUWA ni: mimọ́ ni fun OLUWA.
Pín
Kà Lef 27