Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Lef 2:3YBCV(Bibeli Mimọ)
Iyokù ti ẹbọ ohunjijẹ na, a si jẹ ti Aaroni, ati ti awọn ọmọ rẹ̀: ohun mimọ́ julọ lati inu ẹbọ OLUWA ni ti a fi iná ṣe.
Pín
Lef 2YBCVLef 2:3BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìyókù nínú ọrẹ ohun jíjẹ náà jẹ́ ti Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀, ó jẹ́ ìpín tí ó mọ́ jùlọ nínú ọrẹ tí a fi iná sun sí OLúWA.
Pín
Lef 2BMYOLef 2:3YCE(Yoruba Bible)
Ohun tí ó ṣẹ́kù ninu ìyẹ̀fun náà di ti Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀. Òun ló mọ́ jùlọ, nítorí pé apá kan ninu ẹbọ sísun sí OLUWA ni.
Pín
Lef 2YCE