Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Joṣ 9:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
wọ́n sì kó ara wọn jọ láti bá Joṣua àti Israẹli jagun.
Joṣ 9:2YCE(Yoruba Bible)
gbogbo wọn parapọ̀, wọ́n fi ohùn ṣọ̀kan láti bá Joṣua ati àwọn ọmọ Israẹli jagun.