Nigbana li ẹnyin o dide ni buba, ẹnyin o si gbà ilu na: nitoriti OLUWA Ọlọrun nyin yio fi i lé nyin lọwọ.
Ẹ̀yin ẹ dìde níbi tí ẹ farapamọ́ sí, kí ẹ sì gba ìlú náà, nítorí OLUWA Ọlọrun yóo fi lé yín lọ́wọ́.
ẹ̀yin yóò dìde kúrò ní ibùba, ẹ ó sì gba ìlú náà. OLúWA Ọlọ́run yín yóò sì fi lé e yín lọ́wọ́.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò