Joṣ 6:25
Joṣ 6:25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Joṣua si gbà Rahabu panṣaga là, ati ara ile baba rẹ̀, ati ohun gbogbo ti o ní; o si joko lãrin Israeli titi di oni-oloni; nitoriti o pa awọn onṣẹ mọ́ ti Joṣua rán lọ ṣamí Jeriko.
Pín
Kà Joṣ 6Joṣ 6:25 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Joṣ 6