Joṣua si dide ni kùtukutu owurọ̀, awọn alufa si gbé apoti OLUWA.
Joṣua dìde ní òwúrọ̀ kutukutu, àwọn alufaa gbé Àpótí Majẹmu OLUWA.
Joṣua sì dìde ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, àwọn àlùfáà sì gbé àpótí ẹ̀rí OLúWA.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò