Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Joṣ 3:8YBCV(Bibeli Mimọ)
Iwọ o si paṣẹ fun awọn alufa ti o rù apoti majẹmu na pe, Nigbati ẹnyin ba dé eti odò Jordani, ki ẹnyin ki o duro jẹ ni Jordani.
Pín
Joṣ 3YBCVJoṣ 3:8BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sọ fún àwọn àlùfáà tí ó ru àpótí ẹ̀rí náà, ‘Nígbà tí ẹ bá dé etí omi Jordani, ẹ lọ kí ẹ sì dúró nínú odò náà.’ ”
Pín
Joṣ 3BMYOJoṣ 3:8YCE(Yoruba Bible)
Pàṣẹ fún àwọn alufaa tí wọ́n gbé Àpótí Majẹmu náà pé, ‘Nígbà tí ẹ bá dé etí odò Jọdani, ẹ wọ inú odò lọ, kí ẹ sì dúró níbẹ̀.’ ”
Pín
Joṣ 3YCE