Joṣ 23:10
Joṣ 23:10 Yoruba Bible (YCE)
Ẹyọ ẹnìkan ṣoṣo ninu yín ni ó ń bá ẹgbẹrun eniyan jà, nítorí pé OLUWA Ọlọrun yín ni ó ń jà fun yín, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣèlérí fun yín.
Pín
Kà Joṣ 23Joṣ 23:10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọkunrin kan ninu nyin yio lé ẹgbẹrun: nitoripe OLUWA Ọlọrun nyin, on li ẹniti njà fun nyin, gẹgẹ bi o ti sọ fun nyin.
Pín
Kà Joṣ 23