Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Joṣ 2:8YBCV(Bibeli Mimọ)

Ki nwọn ki o tó dubulẹ, o gòke tọ̀ wọn lọ loke àja

Joṣ 2:8BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Kí àwọn ayọ́lẹ̀wò náà tó sùn ní alẹ́, ó gòkè tọ̀ wọ́n lọ lókè àjà.

Joṣ 2:8YCE(Yoruba Bible)

Kí àwọn amí meji náà tó sùn, Rahabu gun òrùlé lọ bá wọn, ó ní