Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Joṣ 2:6YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn o ti mú wọn gòke àja ile, o si fi poroporo ọ̀gbọ ti o ti tòjọ soke àja bò wọn mọlẹ.
Pín
Joṣ 2YBCVJoṣ 2:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
(Ṣùgbọ́n ó ti mú wọn gòkè àjà ó sì fi wọ́n pamọ́ sí abẹ́ pòròpòrò ọkà tó tò jọ sí orí àjà.)
Pín
Joṣ 2BMYOJoṣ 2:6YCE(Yoruba Bible)
Ṣugbọn ó ti kó wọn gun orí òrùlé rẹ̀, ó sì ti fi wọ́n pamọ́ sáàrin pòpórò igi ọ̀gbọ̀ tí ó tò jọ sibẹ.
Pín
Joṣ 2YCE