Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Joṣ 2:13YBCV(Bibeli Mimọ)
Ati pe ẹnyin o pa baba mi mọ́ lãye, ati iya mi, ati awọn arakunrin mi, ati awọn arabinrin mi, ati ohun gbogbo ti nwọn ní, ki ẹnyin si gbà ẹmi wa lọwọ ikú.
Pín
Joṣ 2YBCVJoṣ 2:13BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
pé ẹ̀yin yóò dá ẹ̀mí baba àti ìyá mi sí; arákùnrin mi àti arábìnrin mi, àti ohun gbogbo tí wọ́n ní, àti pé ẹ̀yin yóò gbà wá là lọ́wọ́ ikú.”
Pín
Joṣ 2BMYOJoṣ 2:13YCE(Yoruba Bible)
Kí ẹ dá baba mi ati ìyá mi sí, ati àwọn arakunrin mi, ati àwọn arabinrin mi, ati gbogbo àwọn eniyan wọn; ẹ má jẹ́ kí á kú.”
Pín
Joṣ 2YCE