Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Joṣ 18:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ̀ya meje si kù ninu awọn ọmọ Israeli, ti kò ti igbà ilẹ-iní wọn.
Pín
Joṣ 18YBCVJoṣ 18:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ṣùgbọ́n ó ku ẹ̀yà méje nínú àwọn ọmọ Israẹli tí kò tí ì gba ogún ìní wọn.
Pín
Joṣ 18BMYOJoṣ 18:2YCE(Yoruba Bible)
Ó ku ẹ̀yà meje, ninu àwọn ẹ̀yà Israẹli, tí wọn kò tíì pín ilẹ̀ fún.
Pín
Joṣ 18YCE