Jon 3:1-3
Jon 3:1-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọ̀RỌ Oluwa si tọ̀ Jona wá lẹ̃keji, wipe, Dide, lọ si Ninefe, ilu nla nì, ki o si kede si i, ikede ti mo sọ fun ọ. Jona si dide, o si lọ si Ninefe, gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa. Ninefe si jẹ ilu nla gidigidi tó irin ijọ mẹta.
Pín
Kà Jon 3