Jon 1:1-2
Jon 1:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
NJẸ ọ̀rọ Oluwa tọ̀ Jona ọmọ Amittai wá, wipe, Dide, lọ si Ninefe, ilu nla nì, ki o si kigbe si i; nitori ìwa buburu wọn goke wá iwaju mi.
Pín
Kà Jon 1NJẸ ọ̀rọ Oluwa tọ̀ Jona ọmọ Amittai wá, wipe, Dide, lọ si Ninefe, ilu nla nì, ki o si kigbe si i; nitori ìwa buburu wọn goke wá iwaju mi.