Joel 2:14
Joel 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ta ni ó mọ̀ bí òun yóò yípadà, kí o sì ronúpìwàdà, kí ó sì fi ìbùkún sílẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀— àní ọrẹ-jíjẹ àti ọrẹ mímu fún OLúWA Ọlọ́run yín?
Pín
Kà Joel 2Joel 2:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Tali o mọ̀ bi on o yipadà, ki o si ronupiwàda, ki o si fi ibukún silẹ̀ lẹhin rẹ̀; ani ọrẹ-jijẹ ati ọrẹ-mimu fun Oluwa Ọlọrun nyin?
Pín
Kà Joel 2