Job 7:6-7
Job 7:6-7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọjọ mi yara jù ọkọ̀ iwunṣọ lọ, o si di lilò li ainireti. A! ranti pe afẹfẹ li ẹmi mi; oju mi kì yio pada ri rere mọ.
Pín
Kà Job 7Ọjọ mi yara jù ọkọ̀ iwunṣọ lọ, o si di lilò li ainireti. A! ranti pe afẹfẹ li ẹmi mi; oju mi kì yio pada ri rere mọ.