Job 6:23
Job 6:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Tàbí, ẹ gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá ni, tàbí, ẹ rà mí padà kúrò lọ́wọ́ alágbára nì’?
Pín
Kà Job 6Job 6:23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Tabi, ẹ gbà mi li ọwọ ọ̀ta nì, tabi, ẹ rà mi padà kuro lọwọ alagbara nì!
Pín
Kà Job 6