Job 29:14
Job 29:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Èmi sì mú òdodo wọ̀ bí aṣọ, ẹ̀tọ́ mi dàbí aṣọ ìgúnwà àti adé ọba.
Pín
Kà Job 29Job 29:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi si mu ododo wọ̀, o si bò mi lara; idajọ mi dabi aṣọ igunwa ati ade ọba.
Pín
Kà Job 29