Ki a ma ri pe emi ndá nyin li are, titi emi o fi kú emi kì yio ṣi ìwa otitọ mi kuro lọdọ mi.
Kí á má rí i, n kò jẹ́ pè yín ní olóòótọ́; títí di ọjọ́ ikú mi ni n óo dúró lórí ọ̀rọ̀ mi, pé mo wà lórí àre.
Kí a má rí i pé èmi ń dá yín láre; títí èmi ó fi kú, èmi kì yóò ṣí ìwà òtítọ́ mi kúrò lọ́dọ̀ mi.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò