Job 14:10
Job 14:10 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn bí eniyan bá kú, a óo tẹ́ ẹ sinu ibojì, bí ó bá ti gbẹ́mìí mì, ó di aláìsí.
Pín
Kà Job 14Job 14:10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn enia kú, a si ṣàn danu; ani enia jọwọ ẹmi rẹ̀ lọwọ, on ha da?
Pín
Kà Job 14