Job 14:1-2
Job 14:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
ENIA ti a bi ninu obinrin ọlọjọ diẹ ni, o si kún fun ipọnju. O jade wá bi itana eweko, a si ke e lulẹ, o si nfò lọ bi ojiji, kò si duro pẹ́.
Pín
Kà Job 14ENIA ti a bi ninu obinrin ọlọjọ diẹ ni, o si kún fun ipọnju. O jade wá bi itana eweko, a si ke e lulẹ, o si nfò lọ bi ojiji, kò si duro pẹ́.