Joh 13:16
Joh 13:16 Yoruba Bible (YCE)
Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé: ẹrú kò ju oluwa rẹ̀ lọ, iranṣẹ kò ju ẹni tí ó rán an níṣẹ́ lọ.
Pín
Kà Joh 13Joh 13:16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Lòtọ, lõtọ ni mo wi fun nyin, Ọmọ-ọdọ kò tobi jù oluwa rẹ̀ lọ; bẹ̃ni ẹniti a rán kò tobi jù ẹniti o rán a lọ.
Pín
Kà Joh 13