Joh 10:29-30
Joh 10:29-30 Bibeli Mimọ (YBCV)
Baba mi, ẹniti o fi wọn fun mi, pọ̀ ju gbogbo wọn lọ; kò si si ẹniti o le já wọn kuro li ọwọ́ Baba mi. Ọ̀kan li emi ati Baba mi jasi.
Pín
Kà Joh 10Joh 10:29-30 Yoruba Bible (YCE)
Ohun tí Baba mi ti fún mi tóbi ju ohun gbogbo lọ. Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè já a gbà mọ́ Baba mi lọ́wọ́. Ọ̀kan ni èmi ati Baba mi.”
Pín
Kà Joh 10Joh 10:29-30 Bibeli Mimọ (YBCV)
Baba mi, ẹniti o fi wọn fun mi, pọ̀ ju gbogbo wọn lọ; kò si si ẹniti o le já wọn kuro li ọwọ́ Baba mi. Ọ̀kan li emi ati Baba mi jasi.
Pín
Kà Joh 10