Jer 4:18
Jer 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Ìwà rẹ àti ìṣe rẹ ló fa èyí bá ọ ìjìyà rẹ sì nìyìí, Báwo ló ti ṣe korò tó! Báwo ló ti ṣe gún ọkàn rẹ sí!”
Pín
Kà Jer 4Jer 4:18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ìwa rẹ ati iṣe rẹ li o ti mu gbogbo ohun wọnyi bá ọ; eyi ni buburu rẹ, nitoriti o korò, nitoriti o de ọkàn rẹ.
Pín
Kà Jer 4