Jer 38:20
Jer 38:20 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn Jeremiah wipe, nwọn kì yio si fi ọ le wọn lọwọ, emi bẹ̀ ọ, gbọ́ ọ̀rọ Oluwa ti mo sọ fun ọ: yio si dara fun ọ, ọkàn rẹ yio si yè.
Pín
Kà Jer 38Ṣugbọn Jeremiah wipe, nwọn kì yio si fi ọ le wọn lọwọ, emi bẹ̀ ọ, gbọ́ ọ̀rọ Oluwa ti mo sọ fun ọ: yio si dara fun ọ, ọkàn rẹ yio si yè.