Jer 31:3
Jer 31:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Oluwa ti fi ara hàn fun mi lati okere pe, Nitõtọ emi fi ifẹni aiyeraiye fẹ ọ, nitorina ni emi ti ṣe pa ore-ọfẹ mọ fun ọ.
Pín
Kà Jer 31Jer 31:3 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA yọ sí wọn láti òkèèrè. Ìfẹ́ àìlópin ni mo ní sí ọ, nítorí náà n kò ní yé máa fi òtítọ́ bá ọ lò.
Pín
Kà Jer 31