Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jer 3:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi si wipe, lẹhin ti o ti ṣe gbogbo ohun wọnyi tan, yio yipada si mi, ṣugbọn kò yipada, Juda alarekereke arabinrin rẹ̀ si ri i.
Pín
Jer 3YBCVJer 3:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo rò pé nígbà tí wọ́n ti ṣe èyí wọn yóò padà, wọn kò padà, Juda aláìgbàgbọ́ arábìnrin rẹ̀ náà sì rí i.
Pín
Jer 3BMYOJer 3:7YCE(Yoruba Bible)
Mo rò pé yóo pada tọ̀ mí wá, lẹ́yìn tí ó bá ṣe àgbèrè rẹ̀ tán ni; ṣugbọn kò pada; Juda arabinrin rẹ̀, alaiṣootọ sì rí i
Pín
Jer 3YCE