Jer 2:11
Jer 2:11 Yoruba Bible (YCE)
Ǹjẹ́ orílẹ̀-èdè kankan tíì pààrọ̀ ọlọrun rẹ̀ rí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn kì í ṣe ọlọrun tòótọ́? Ṣugbọn àwọn eniyan mi ti pààrọ̀ ògo wọn, wọ́n ti fi ohun tí kò ní èrè pààrọ̀ rẹ̀.
Pín
Kà Jer 2Jer 2:11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Orilẹ-ède kan ha pa ọlọrun rẹ̀ dà? sibẹ awọn wọnyi kì iṣe ọlọrun! ṣugbọn enia mi ti yi ogo wọn pada fun eyiti kò lerè.
Pín
Kà Jer 2