Jer 17:10
Jer 17:10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi, Oluwa, ni iwá awari ọkàn enia, emi ni ndan inu wò, ani lati fi fun olukuluku gẹgẹ bi ọ̀na rẹ̀, ati gẹgẹ bi eso iṣe rẹ̀.
Pín
Kà Jer 17Jer 17:10 Yoruba Bible (YCE)
Èmi OLUWA ni èmi máa ń wádìí èrò eniyan, tí èmi sì máa ń yẹ ọkàn eniyan wò, láti san án fún olukuluku gẹ́gẹ́ bí ìṣe rẹ̀, ati gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Pín
Kà Jer 17