A. Oni 6:17
A. Oni 6:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Gideoni sì dáhùn pé, nísinsin yìí tí mo bá bá ojúrere rẹ pàdé, fún mi ní ààmì pé ìwọ ni ń bá mi sọ̀rọ̀.
Pín
Kà A. Oni 6A. Oni 6:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
On si wi fun u pe, Bi o ba ṣepe mo ri ore-ọfẹ gbà li oju rẹ, njẹ fi àmi kan hàn mi pe iwọ bá mi sọ̀rọ.
Pín
Kà A. Oni 6