Jak 3:5
Jak 3:5 Yoruba Bible (YCE)
Bẹ́ẹ̀ ni ahọ́n, ẹ̀yà ara kékeré ni, ṣugbọn ìhàlẹ̀ rẹ̀ pọ̀. Ẹ wo bírà tí iná kékeré lè dá ninu igbó ńlá!
Pín
Kà Jak 3Jak 3:5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bẹ̃ pẹlu li ahọn jẹ ẹ̀ya kekere, o si nfọnnu ohun nla. Wo igi nla ti iná kekere nsun jóna!
Pín
Kà Jak 3