Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jak 2:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori bi ọkunrin kan ba wá si ajọ nyin, pẹlu oruka wura, ati aṣọ daradara, ti talakà kan si wá pẹlu li aṣọ ẽri
Pín
Jak 2YBCVJak 2:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí bí ọkùnrin kan bá wá sí ìpéjọpọ̀ yín, pẹ̀lú òrùka wúrà àti aṣọ dáradára, tí tálákà kan sì wá pẹ̀lú nínú aṣọ èérí
Pín
Jak 2BMYOJak 2:2YCE(Yoruba Bible)
Bí àpẹẹrẹ, bí ẹnìkan bá wọ àwùjọ yín, tí ó fi òrùka wúrà sọ́wọ́, tí ó wọ aṣọ tí ń dán, tí talaka kan náà bá wọlé tí ó wọ aṣọ tí ó dọ̀tí
Pín
Jak 2YCE