Jak 1:17
Jak 1:17 Yoruba Bible (YCE)
Láti òkè ni gbogbo ẹ̀bùn rere ati gbogbo ẹ̀bùn pípé ti ń wá, a máa wá láti ọ̀dọ̀ Baba tí ó dá ìmọ́lẹ̀, baba tí kì í yí pada, tí irú òjìji tíí máa wà ninu ìṣípò pada kò sì sí ninu rẹ̀.
Pín
Kà Jak 1Jak 1:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Gbogbo ẹ̀bun rere ati gbogbo ẹ̀bun pipé lati oke li o ti wá, o si nsọkalẹ lati ọdọ Baba imọlẹ wá, lọdọ Ẹniti kò le si iyipada tabi ojiji àyida.

Kà Jak 1Jak 1:17 Yoruba Bible (YCE)

Kà Jak 1