IWỌ iba jẹ fà awọn ọrun ya, ki iwọ si sọkalẹ, ki awọn oke-nla ki o le yọ́ niwaju rẹ.
Ò bá jẹ́ fa awọsanma ya kí o sì sọ̀kalẹ̀, kí àwọn òkè ńlá máa mì tìtì níwájú rẹ
Ìwọ ìbá fa ọ̀run ya kí o sì sọ̀kalẹ̀ wá, tí àwọn òkè ńlá yóò fi wárìrì níwájú rẹ!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò