Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Isa 62:6YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi ti fi awọn alore sori odi rẹ, iwọ Jerusalemu, ti kì yio pa ẹnu wọn mọ lọsan ati loru titilai: ẹnyin ti nṣe iranti Oluwa, ẹ máṣe dakẹ.
Isa 62:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ti fi olùṣọ́ ránṣẹ́ sórí odi rẹ ìwọ Jerusalẹmu; wọn kì yóò lè dákẹ́ tọ̀sán tòru. Ẹ̀yin tí ń ké pe OLúWA, ẹ má ṣe fúnra yín ní ìsinmi
Isa 62:6YCE(Yoruba Bible)
Jerusalẹmu, mo ti fi àwọn aṣọ́de sí orí odi rẹ; lojoojumọ, tọ̀sán-tòru, wọn kò gbọdọ̀ panumọ́. Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń rán OLUWA létí, ẹ má dákẹ́.