Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Isa 52:2

Isa 52:2 Bibeli Mimọ (YBCV)

Gbọ̀n ekuru kuro li ara rẹ, dide, joko, iwọ Jerusalemu: tú ọjá kuro li ọrùn rẹ, iwọ ondè ọmọbinrin Sioni.

Pín
Kà Isa 52

Isa 52:2 Yoruba Bible (YCE)

Dìde, gbọnranù kúrò ninu erùpẹ̀, ìwọ Jerusalẹmu tí ó wà ninu ìdè. Tú okùn tí a dè mọ́ ọ lọ́rùn kúrò, ìwọ Sioni tí ó wà ninu ìdè.

Pín
Kà Isa 52

Isa 52:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Gbọn eruku rẹ kúrò; dìde sókè, kí o sì gúnwà, Ìwọ Jerusalẹmu. Bọ́ ẹ̀wọ̀n tí ń bẹ lọ́rùn rẹ kúrò, ìwọ ọ̀dọ́mọbìnrin ìgbèkùn Sioni.

Pín
Kà Isa 52
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò