Isa 3:8 - Compare All Versions

Isa 3:8 YBCV (Bibeli Mimọ)

Nitori Jerusalemu di iparun, Juda si ṣubu: nitori ahọn wọn ati iṣe wọn lòdi si Oluwa, lati mu oju ogo rẹ̀ binu.

Isa 3:8 YCE (Yoruba Bible)

Nítorí Jerusalẹmu ti kọsẹ̀, Juda sì ti ṣubú. Nítorí ọ̀rọ̀ ẹnu wọn ati ìṣe wọn lòdì sí OLUWA, wọ́n ń tàpá sí ògo wíwà rẹ̀.

Isa 3:8 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Jerusalẹmu ń ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n Juda ń ṣubú lọ, ọ̀rọ̀ àti ìṣe wọn lòdì sí OLúWA, láti mú ojú ògo rẹ̀ bínú.